ONISE IYANU SONG LYRICS
ONISE IYANU
CHORUS:
Tani ba fiowe,
(Onise Iyanu), Taniba Fiowe oo, (Onise Iyanu),
Koseni tale fi
owe, Iwo L’onise Iyanu x2
SOLO:
Omu aro larada
(Onise Iyanu), Afoju riran (Onise Iyanu), Adit n gboran oo (Onise iyanu),
Hes a Mighty God
(Onise Iyanu), Koseni talefiowe, Iwo L’onise Iyanu.
CHORUS:
Tani ba fiowe,
(Onise Iyanu), Taniba Fiowe oo, (Onise Iyanu),
Koseni tale fi
owe, Iwo L’onise Iyanu x2
SOLO:
Oji oku dide
(Onise Iyanu), Oni Lazaru jade wa (Onise Iyanu), Koseni tale fi owe, Iwo
L’onise Iyanu
CHORUS:
Tani ba fiowe,
(Onise Iyanu), Taniba Fiowe oo, (Onise Iyanu),
Koseni tale fi
owe, Iwo L’onise Iyanu x2
SOLO:
Eko rin si Oba
Ogo, Iyanu lo lorun wa, Egbe Oruko Jesu ga, Agbara re wasibe. Jesu to so eru wa
dayo, To mu ibanuje tan. Ori iyin leti eleshe, Iye ati ilera.
CHORUS:
Tani ba fiowe,
(Onise Iyanu), Taniba Fiowe oo, (Onise Iyanu),
Koseni tale fi
owe, Iwo L’onise Iyanu x2
-Song By Ruth Oluwadamilola
-Written By Domzy
Comments
Post a Comment